JAMB 2023 Yoruba 2023 Q15: ÀṢÀ ÀTI ÌṢẸ YORÙBÁ (IBÉERE)Èwo ni won kií fi ṣe àdùrà fún ọmọ ikókó ni ibi ṣọmọlórúkọ?
JAMB 2023 Yoruba 2023 Q16: ÀKAYÉ. Instructions: Ka awon ayọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó télé won. Ọpọlọpọ oúnje ni ó wà ní ilẹ̀…
JAMB 2023 Yoruba 2023 Q11: ÀṢÀ ÀTI ÌṢẸ YORÙBÁ (IBÉERE)Èwo ni oríkì àbíso fún ọmọkùnrin nínú àwọn wonyìi?
JAMB 2023 Yoruba 2023 Q12: ÀṢÀ ÀTI ÌṢẸ YORÙBÁ (IBÉERE)Gbogbo àwọn orúko wonyìi jẹ́ ti àbíkú ni ilè Yorùbá àyàfi
JAMB 2023 Yoruba 2023 Q9: ÀṢÀ ÀTI ÌṢẸ YORÙBÁ (IBÉERE)Èwo ninu awon ewi alohùn wonyìi ni ó wọpọ ni agbegbe Òndó?
JAMB 2023 Yoruba 2023 Q10: ÀṢÀ ÀTI ÌṢẸ YORÙBÁ (IBÉERE)Àwọn wo ni àwọn Yorùbá ń kí ni ‘Àrẹpọ́n àrèdú o’?