Dahun àwon ìbéèrè wọnyí. ÌPÍN A: ÉDÉ AKAYE Ka àwọn ayọkà ìsàlẹ̀ wọnyí kí o si dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ́lé okookan wọn. Aago márùn-ún ìdájí ni Ṣeun…
Dahun àwon ìbéèrè wọnyí.
ÌPÍN A: ÉDÉ AKAYE
Ka àwọn ayọkà ìsàlẹ̀ wọnyí kí o si dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ́lé okookan wọn.
Aago márùn-ún ìdájí ni Ṣeun ti jí jáde nílé lo wo oko tí ó n lo sí Ìdanrè. Ìbúdóko Ojóta ni ó lo kí ó lè tètè ri oko wo. Aago mewaá ni oko tó kún. Kí wón tó dé Ṣagámú ni oko ti bèrè síí yọnu. Agbára káká ni wọn fi dé ilé-isé-atókòse kan lébàá Ogbolú. Kí wón tó rí oko se tán, aago mérin irolé ti lù. Gére tí wọn dé ljèbú-òde ni oko bá tún denu kolẹ. Ojú ojó ti ń po fírí, aago méje ti féréé lù ki wọn tóó dé Ore níbi ti awako ti so pé òun ò lè lo mo. Ṣeun wá gbà pé òun ti ṣi rin ni ojó náà. Ojó tí kò níí gbagbé láéláé ni ojó náà jé fún un. Ò ronú eni ti òun kókó jí rí ni ojó yìí, kò rántí; ó féé mo bí yóò se yera fún onítóhún. Ótó wákátí kan tí ó ti ń wá oko miíràn ti kò rí. Lójijì ni òjò bèrè síí ro. Òjò phún kò tile fu enikankan lára tí ó fi bèrè síí rò.
Abé òrùlé ni ó sá si títí di aago mésàn-án àbò ki won tóó rí oko tí ó kò méta nínú won lo. Déédéé aago méjìlà abo òru ni ó tó wo Ìdànrè ni ojó tí à ń wí yìí.
Bí aago mélòó ni awako tóó so pé òun kò lè lo mo?
The driver said he could not continue at 7 o’clock when they reached Ore. This is when the vehicle problems stopped the journey.
Earlier times show different parts of the trip. Seven o’clock specifically marks when the driver quit.
Time markers help us track story events. Noting when things happen shows the sequence clearly.
Was this explanation helpful?