II. Táyé: E má kú ojó méta kan. Adéolá: Awa mà niyen o. Táyé: E ṣáá kú ọwọ́ lómi iyá Kúnbi, égbọ́n rẹ (Oláídé, oré won, dé bá won lórí…
II.
Táyé: E má kú ojó méta kan.
Adéolá: Awa mà niyen o.
Táyé: E ṣáá kú ọwọ́ lómi iyá Kúnbi, égbọ́n rẹ
(Oláídé, oré won, dé bá won lórí idúró).
Oláídé: A báríká ọmọ tuntun o, Olorun á wò ó.
Adéolá: Adún á kári o.
Táyé: Báwo wá ni ètò ìsomolórúko?
Adéolá: Bí àwọn bábá wa ti í se é náà ni. A bó o ti gbagbé? Qmokùnrin, ojó mésàn-án, Qmobinrin, ojo méje, ti ti ibeji je ojó méjo.
Oláídé: E sáá féé se é bi wọn ti í se ê, kí ó baà rí bi ó ti máa ń rí.
Adéolá: Okùnrin kan, obinrin kan kúkú ni àwọn ọmọ náà. Mo tilè gbó pé eyí okùnrin dojú bole, èyí obinrin gbé ibi kórùn.
Táye: Ha! Àjàyí àti Aìná nìyen.
Adéolá: Abósédé tí ó je àbíkéyin iyá wa ti lọ ra àwọn ohun-èlò ìsomolórúko bíí ìrèké, oyin, àádùn, obi, orógbó àti ataare ní ojà-oba.
Oláídé: À jé pé kí obi bikú danù, kí orógbó gbó wọn sáyé.
Adéolá: Àse o, a ó tún máa ríra lójó méfa òní.
Ta ni ó dé bá Táyé àti Adéolá níbi tí wọn tí fi soro?
The note in brackets says Oláídé, oré won, dé bá won: “Olaide, their friend, joined them”. So Olaide is the person who arrived while Taye and Adeola were talking.
Abosede is Adeola’s youngest sibling and has gone to buy the naming items. Ajayi and Aina are the newborn twins, so they cannot arrive.
Was this explanation helpful?
Something wrong or missing? Tell us — we read every report and fix issues fast.