Iya náà ra èwà sè tà Orò ise mélóó ni ó wà nínú gbólóhùn yìí?

Iya náà ra èwà sè tà Orò ise mélóó ni ó wà nínú gbólóhùn yìí?

  1. Okan
  2. Méjì
  3. Meta ✓
  4. Mérin

Explanation

This sentence has three action words: “ra” (buy), “se” (cook), and “ta” (sell). Count each action the woman does.

One action word would not show all the woman does. Four would be too many for this sentence.

Finding verbs helps you understand what happens in a sentence. Each verb shows a separate action.