Yoruba 2023 Q6: ÀṢÀ ÀTI ÌṢẸ YORÙBÁ (IBÉERE) Òrìṣà wo ni àwọn Yorùbá máa ń bọ láti fi se iránti awon baba ńlá won tí ó ti kú?

ÀṢÀ ÀTI ÌṢẸ YORÙBÁ (IBÉERE)

Òrìṣà wo ni àwọn Yorùbá máa ń bọ láti fi se iránti awon baba ńlá won tí ó ti kú?

  1. Egúngún ✓
  2. Ẹṣù
  3. Ògún
  4. Ṣàngó

Explanation

The correct answer is “Egúngún”.

This is a Yoruba language question testing vocabulary and grammar comprehension.