Yoruba 2023 Q16: ÀKAYÉ. Instructions: Ka awon ayọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó télé won. Ọpọlọpọ oúnje ni ó wà ní ilẹ̀…

ÀKAYÉ.
Instructions: Ka awon ayọkà ìsàlẹ̀ yìí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó télé won.
Ọpọlọpọ oúnje ni ó wà ní ilẹ̀ Yorùbá, oúnje tí ó dàbí oba àwọn oúnje ní ilẹ̀ Yorùbá ni ìṣu, oúnje tí a máa ń fi ìṣu je jù ní ìyán, a si tún le è je ni ìṣu odò, arèhin-gba-kùmò, olóbè-kú àsènù, pètísán àti béèbée lọ.
Púpọ́ nínú àwọn ìṣu wonyìí ni ó dára láti je ìyán, àwọn bèé ni ìṣu odò, arèhin-gba kumo, efùrù, gàmbàrí, arò àti béèbée lọ. Bi a se ń gún won ni won yóò máa gba omi ti won yóò sì máa wú fún. Àwọn ìṣu miíràn wà tí ó jẹ́ wí pé kó ṣe ìyán rárá ohun kò kí a ba se fún kò ni ń wọ́n je ìṣu tàbí síṣe àsárò, àwọn ìṣu tàbí síṣe àsárò, àwọn ìṣu lójú olójé-kú-àsènù, pètísán, òlò, ewùrà àti ẹ̀ṣúrú. Ìgba miíràn a lè fi àjẹku ìṣu lópolopo awon lìjẹbú féràn àmàlà ìṣu lópolopo àwọn Ìjẹbú féràn ìkókoré ti won fi ewùrà ṣe, a tún rí àwọn oúnje miíràn bíi àgbàdo, gbáágùdá, ògèdẹ̀, ìrèsì, ọ̀kà bàbà àti béèbée lọ.
Yatò sí àwọn oúnje wonyìi, àwọn Yorùbá féràn obẹ̀ púpọ́ nítoríí obẹ̀ ni a fi ń je ọpọlọpọ̀ àwọn oúnje tí a ménubà saájú wonyìí.
Dáhun àwọn ibéèrè wónyí

Irú oúnje wo ni àwọn Ọyọ́ féràn?

  1. Àgbàdo
  2. Àmàlà ✓
  3. Ewùrà
  4. Ìyán

Explanation

The correct answer is “Àmàlà”.

This is a Yoruba language question testing vocabulary and grammar comprehension.