ÀKAYÉ KÍN-ÍN-NÍ Instruction: Ka àwọn ayọkà ìsàlè yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tèlé wọn. Tádé, Tolá, Búkì, àti Solá je oré tímó-tìmó, sùgbón…
ÀKAYÉ KÍN-ÍN-NÍ
Instruction: Ka àwọn ayọkà ìsàlè yìí, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tèlé wọn.
Tádé, Tolá, Búkì, àti Solá je oré tímó-tìmó, sùgbón Tádé àti Tólá ti je oré láti igbà tí wón ti wà ní ilé iwé alákoóbèrè kí wón tó padé Búkì àti Solá ní ilé-iwé gírama. Àwon órè wonyi jo máa ń se àsepò, bíí àsọ rìrà, oùnje àjepo, ìwé kíkà papò, bàtà rìrà àti ìrun dídi. Bákan ‘náà ni gbogbo ǹkan wọn máa ń rí, báyìí ni àwon órè wonyìí se ti wọn fí jáde ilé-iwé gírama tí wón sì dé ilé-iwé gíga. Ní ilé iwé gíga yìí ni wọn ti pàdé Tolú àti Dàpò ti wọn je ore, inú àwọn òré méjì yìí kò dùn sí àwọn òré mérin wònyì nítoṛi bí wón se ń ran ara wọn lówó lénu èkó, nínú ìdánwò àti ìrànlọwọ owọ, wọn sì ń wá onà láti da àárín wọn rú. Ní ojó kan, àwọn òré méjì yìí lo bá Tádé, wón ní Tólá so wí pé òun ni Tádé máa ń jí wò nínú ìdánwò bákan náà ni wón tún lo bá Tólá, wọn ni Tádé so wí pé nipasè tràǹlówó owó òun ni Tolá fi ń lo sí ilé-iwé, nítoṛi àwọn òbi rè jé táláká. Orò yìí dá ìjà sílè láárín Tádé àti Tólá tóbéé tí ìjà náà ran Búkì àti Solá nítoṛi wí pé Tádé ní Búkì ń gbè lehin Tólá tí Tólá náà si ni èhin Tádé ní Solá wà. Orí ìjà yìí ni àwọn òre wonyi wà tí wọn fí se ìdánwò àsejáde eyì tí ó se àkóbá fún wọn nínú èsì ìdánwò àsejáde wọn.
Dáhùn àwọn ìbéèrè wònyi.Àwon wo ni ore méjì àkókó?
Explanation
The passage says Tade and Tola were friends from primary school. They met before they knew Buki and Sola. This makes them the first two friends.
Later in secondary school, they met Buki and Sola. So the friendship of Tade and Tola is the oldest. It started earliest.
Understanding timelines in stories helps you answer “when” questions. Pay attention to words like “first” and “before.”